Gongo so! Okunrin(18yrs), Obirin (17yrs) se igbeyawo alarinrin

Omokunrin eni odun mejidinlogun ati omobirin eni odun metadinlogun ni won ti se igbeyawo alarinrin bayii ni ipinle Abia. Aimoye awon ebi ati...
Read More

Ise ashewo ni mo n se, iyen ko je tuntun- Omo Olosho yara patapata

Okan ninu awon omoge onidodo to pe oruko ara re ni Erling Carlos ti inagije re si n je Roman Goddess lo ti pada jewo ni gbangba wi pe, ise a...
Read More

Ojoyubirin ti fi omi gbigbona bo ara omo orogun re torotoro

Ojowubirin kan lo ti fi igbonara da omi gbigbona si ara omo orogun re bayii ni ipinle Kastina. Inu irora nla ni omo naa wa lowolowo bayii ni...
Read More

Aare orileede Uganda se abewo si Buhari lonii niluu Abuja

Aare ile UgandaYoweri Kaguta Musveni pelu aya re, Janet Museveni, se abewo si ilu Abuja nibi ti Aare Muhammadu Buhari ati aya re, ti gbe gba...
Read More

Awon aye ti n so nipa akikanju obirin ti n wa oriire fun oko re

Ti okunrin ba mu inu iyawo re dun, kosi iru nnkan ti obirin naa ko le se fun oko re. Lara iru nnkan bee ni ki okunrin je olotito si aya re.
Read More

IFA fohun jade: Wande Abimbola ti so idi ti jegudujera fi n gbile lorileede Nigeria

Ohun to daju ni wi pe, Edua ko fero, omo araye ko si fe ododo. Ojogbon Wande Abimbola, eni to ti fi igba kan je oga agba Yunifasiti Ile Ife,...
Read More