"Mi ò le kọ isẹ ìlù lilu lai ma kọ èdè Yoruba" - Ayantunde Anselm Ramacher omo ilu Germany

Se mo le dupe tan lọwọ Ogbeni Ayantunde Anselm Ramacher?

Ayantunde Anselm Ramacher pelu Olayemi Oniroyin


Ti won ba pe eniyan ni ọmọluabi ati eniyan ti o ni ẹmi irẹlẹ, Ọgbẹni Ayantunde ni apẹẹrẹ to pegede julọ.


Ogbẹni Ayantunde darapọ mọ eto mi, Gbedemuke, lọjọ kẹẹdogun osu kẹwaa odun yii (2016) lati se alaye nipa irin-ajo won nipa ise ilu ati ibasepo won pelu awon ọmọ Yoruba.


Alaye Ogbeni Ayantunji wa NIBI


Orisun: www.radiodiaspora.com.ng
Share on Google Plus

About Olayemi Olatilewa

www.olayemioniroyin.com

Whatsapp +2348032394964

0 comments:

Post a Comment