Ẹja ti n won pe ni Shellfish se awon eniyan ni kayefi lode agbaye

E ma jẹ ki n parọ fun yin, aimoye ohun abẹmi lo wa nisalẹ omi eleyii ti Olorun da fun igbadun omo eniyan.
Orisii ẹja kan ni yii eleyii ti won pe oruko rẹ ni Shellfish.
 Bi eniyan ba ri eja yii pelu ẹfọ ṣọkọ ati ẹba tabi amala dudu, aye to dun to ko si.
Won eniyan tun le din ko ma fi mu waini nirọlẹ leyin isẹ ojo. Bakna naa ni ẹ le fi mu gari

Share on Google Plus

About Olayemi Olatilewa

www.olayemioniroyin.com

Whatsapp +2348032394964

0 comments:

Post a Comment