Ewi tuntun: Akeem Lasisi ti pada pelu TURNING POINT


Akeem Lasisi
Isẹ ewi je isẹ ẹ̀mí, ímísí eleyii to tayọ ọgbọn ori lasan ati lakaaye. Awon kan tilẹ se apejuwe ojulowo ewi gẹgẹ bi isura iyebiye. Boya eyi lo mu Olanrewaju Adepoju salaye ninu ewi re kan wi pe,  
"akewi ti won ba ja lólè ise ọpọlọ ko yato sẹni tọmọku lọwọ rẹ"
Eleyii se apẹrẹ bi ojulowo ewi se tẹwọn to. Lara ọna ti awon ojulowo akawi maa n gba lo ise won ni lati ta awon eniyan jigiri, mu won ronujinlẹ, lati mu won lokan le ati lati fun won ni ireti nla.


Akeem Lasisi ti doosa ninu isẹ ewi to lapọnja ayafi taa ba fẹ pe omi dudu laró. Pupọ ninu awon isẹ rẹ lo si ti gba irawọ meje pẹlu ami-ẹyẹ kaakiri ile adulawọ. 

Tuntun ni eleyii to pe ni TURNING POINT, o ya e je ka lọ kofa ise ọpọlọ gidi.


Share on Google Plus

About Olayemi Olatilewa

www.olayemioniroyin.com

Whatsapp +2348032394964

0 comments:

Post a Comment