Ajalu sele niluu London: eniyan marun un ku, ogoji farapa

Awon eniyan ti won fura si gege bi alakatakiti agbesunmomi gbiyanju lati kolu ile igbimo ile Biritiko lana, 22:03:07. 


E yii ni won se nigba ti won wako sare pa awon eniyan lori afara Westminster nipa igbiyanju won lati kolu ile igbimo. Awon eniyan bi marun un ni won ba isele naa lo nigba ti awon bi ogoju farapa.
Gbogbo aye ti n gboriyin fun awon osise alaabo fun akiyan won latari wi pe isele naa ko bo sori. Sugbon sa, awon odaran naa gun okunrin olopaa kan lobe pa ti oruko re n je Palmer, eni odun mejidinlaadota. Isele yii ba okan awon eniyan je puo
Sugbon sa, olootu ile Biritiko ti ni ilu oba ko ni sinmi lati gbogun ti awon eniyan ti won ba n gbiyanju lati da alaafia ilu naa laamu. 

E ku etileko fun akotun iroyin










Share on Google Plus

About Olayemi Olatilewa

www.olayemioniroyin.com

Whatsapp +2348032394964

0 comments:

Post a Comment