Aye Akamara: Leyin 21yrs to ti n wa omo, odun meta lo tun fi ru oyun akobi re

 

Eniyan to ba ni ko saye, won ti "sample" e ri ni. Errk. 

Gege bi Olanrewaju Adepoju se so ninu ewi re, oni eni aye ba da yerepe adanwo si lagbada, ti onitoun ba ri omo awo ko ni pegan. 

Olayemi mo seba awon agba o!

Arabirin yii lo ti n wa omo lati nnkan bi odun mokanlelogun (21yrs) ti ko gbo pa. Iyalenu ibe ni wi pe, igba to tun wa loyun odun meta ati osu meji lo fi ru oyun naa.

Iwuafor Juliet to je ibatan re lo royin faye

 
Adura mi ni wi pe, awon ti n woju Oluwa fun omo rere, Edua oke yoo dawon lohun ni kiakia. Omo naa yoo si ba won kale. Amin
Share on Google Plus

About Olayemi Olatilewa

www.olayemioniroyin.com

Whatsapp +2348032394964

0 comments:

Post a Comment