"Ojo kan n bo, e ma de ile iwosan ko ni si dokita kankan ni be" Dokita kan lo so bee

   
Ti won ba beere kilode tigun fi pa lori dandan ni ko ri wi. Ti won ba si beere kilode ti akalamagbo fi yoyo gege lorun, dandan ni ki oun naa riso. 
 
Awon Yoruna si bo, won ni arokan lo n fa ekun ti eniyan sun ti kii dake.
 
Okunrin Dokita kan kan lo fi ero re han lori ayelujara nipa bi nnkan se n lo leka eto ilera ile yii, e gbo ohun to wi:Share on Google Plus

About Olayemi Olatilewa

www.olayemioniroyin.com

Whatsapp +2348032394964

0 comments:

Post a Comment