Buhari yan fanda ni mosalaasi jimoh lonii

Image may contain: 3 people, beard 
Leyin bi ose bi meloo kan ti awon eniyan ko ti foju kan Aare Buhari, Sai Baba pada jade wa kirun jimoh lonii ojo karun un osu karun odun 2017. Latari ailera PMB, orisiirisii aheso oro ni awon eniyan ti n so kaakiri pelu bi oko Aisha se poora loju taye. 

Sugbon sa, Buhar ti pada fi ara re han pada, eleyii to si n fidi re mule wi pe, alaafia ni baba wa.
Share on Google Plus

About Olayemi Olatilewa

www.olayemioniroyin.com

Whatsapp +2348032394964

0 comments:

Post a Comment