Kini yoo sele ti Ambode ba le awon danfo wole nipinle Eko?

 
Gomina Ipinle Eko, Ogbeni Akinwunmi Ambode, ti fi da awon olugbe ipinle re loju wi pe, ijoba oun si wa lori wi pe, awon danfo akero ni lati kuro loju popona wa. 

O ni ti a ba n gbero lati figagbaga pelu awon ilu okeere nla, a ni lati mu awon kan to le duro bi abawon kuro lawujo wa. O ni awon oko bogini nla bi awon ilu nla ni yoo wa loju popona wa leyii ti awon danfo ba kogba wole. 

Bakan naa lo si fi da awon eniyan loju wi pe, awon to n wa oko danfo naa ni ijoba yoo gba senu ise eleyii ti ko fi ni faye sile fun airise awon ti won wa danfo tele. Koda, awon ti ijoba yoo gba yoo ju iye awon awako danfo lo.
Share on Google Plus

About Olayemi Olatilewa

www.olayemioniroyin.com

Whatsapp +2348032394964

0 comments:

Post a Comment