Lonii ojo ibi Seun Egbegbe, enikan to ku pelu re ni yii

Awon Yoruba bo, won ni ko ni buru ko ma ku enikan moni. Oni ni ojo ibi Seun Egbegbe, ololufe re, Oyenike Yusuf, si ni eni akoko ti yoo ki ku oriire. 

Oyenike salaye ojo oni gege bi ojo ayo nitori oni naa ni won so omo won tuntun loruko eleyii ti Nike bi lose to koja.
Inu ogba ewon si ni Seun Egbegbe wa latari esun ole ati jibiti.
Share on Google Plus

About Olayemi Olatilewa

www.olayemioniroyin.com

Whatsapp +2348032394964

0 comments:

Post a Comment