[Foto] Swagger ni Kemi Olunloyo gbe jade lati inu ewon lonii

Pelu idunnu ati ayo ni Kemi Olunloyo fi jade lonii nigba ti won tu sile logba ewon to wa ni Pota.
Arabirin oniroyin ayelujara yii ni won timole bi osu meta seyin, leyin igba ti won fi esun ibaniloruko je kan an

Share on Google Plus

About Olayemi Olatilewa

www.olayemioniroyin.com

Whatsapp +2348032394964

0 comments:

Post a Comment