Oju Mercy Aigbe dile oba to jo

 
Leyin opolopo laasigbo ti Mercy Aigbe koju lati odo oko re, Lanre Gentry, eni to fi ese ba oju omobirin nas je lati ma wulo mo fun un.
Leyin eyi, ohun ti a gbo wi pe, oserebirin naa gba ilu London lo fun itoju to peye.

Abajade itoju naa lo pada so oju Mercy di rigindin pada loju awon ololufe re kaakiri agbaye.
Oro Mercy ni a le fi we ile oba to jo, eleyii to pada fi kun ewa re lopolopo.

Share on Google Plus

About Olayemi Olatilewa

www.olayemioniroyin.com

Whatsapp +2348032394964

0 comments:

Post a Comment